HapMap Project logo
Asepọ HapMap ti Gbogbo Agbaye
 

Ibusọ | Nipa Asepọ | Esi | Itẹjade | Tutorial |

中文 | English | Français | 日本 | Yoruba
About the HapMap
Kinni HapMap?
Orisun iwon-Jiini (Haplotypes)
Anfani
Awon Eya ti a ti se iwadi
Majeobaje
Iwe Idarapo mo iwadi
Community Advisory Groups(CAG)
Ilana Agbekale Esi Iwadi
Ilana lilo Esi Iwadi
Guidelines For Referring to HapMap Populations
 
Project Information
Nipa Asepọ
Itẹjade HapMap
HapMap Tutorial
Olukọwesi HapMap
Alajọşe HapMap
Ẹda oju iwe yi ni ilu Japani
 
Useful Links
HapMap Project Press Release
NHGRI HapMap Page
NCBI Variation Database (dbSNP)
Japanese SNP Database (JSNP)
Bawo ni Ilana HapMap yi yio şe şe mutunmuwa ni anfani

Ilana HapMap yio şe awa enia ni anfani nipasẹ, pipese elo nlanla fun awọn oluşewadi ipa ti jiini nko ninu aisan ati bi ara wa ti şe mba ogun mu tabi ti ko bamu. Bi aba ti mọ awọn iyatọ inu jiini wọnyi, awọn oluwadi le kọ imọ ti o peye lori orisun aisan ati awọn ọna ti o peye ju lati wa wọn jade ati lati şe itọju wọn.

A ko le ti ipasẹ HapMap yi nikan mọ nipa aisan abi ilera. Amọ nipa pipese ilana yi, HapMap yio je ki awọn oluwadi orisirisi fi iwọn-jiini lati awọn enia to ni aisan we ti eni ti ko ni aisan lati tipasẹ iru ayewo bẹ mọ ipa ti jiini nko ninu aisan. Ti iwọn-jiini kan ba wọpọ lara awọn alaisan ti ko si pọ pupọ lara awọn ti ko ni aisan, eleyi fi apẹrẹ han wipe ti a ba tọ pinpin iwọn-jiini bẹ a le şe alabari jiini ti o nfa aisan yi gangan. Awọn aisan bi kansa, ẹjẹ ruru, aisan itọ şuga, ati ikọ-gbẹmimi jẹ irufẹ awọn aisan ti ilana yi le dara fun iwadi wọn. Itagbọn kan fi ye wa wipe awọn iwọn-jiini ti o wọpọ, ni nfa aisan to wọpọ. Lotọ, a ko ti ni imọ to lati mọ oye ọgbọn yi, amọ iba ohun ti a ti ri fi oye ye wa wipe ootọ wa nbẹ.

A ko le sọ irufẹ anfani ti iwadi HapMap yi yio gbe saye lọjọ iwaju. O şeşe ki o jẹ ki a le şe itọju alaisan ni ọna ti o peye fun ẹnikankan wa, ti yio si din jamba ogun lilo ku. A si le jagbọn ohun ti o njẹ ki awọn enia pẹ laye ju arawọn lọ, tabi ti ki i jẹ ki aisan şe ẹni Ð eleyi si le di ohun anfani nla lọjọ iwaju fun mutunmuwa. Gẹgẹbi ohunkohun ti o ba jẹ titun, HapMap yio ni awọn anfani ati ewu ti a ko ro tẹlẹ, ti a ko si mura de, jade.

Gẹgẹbi ohunkohun ti o ba jẹ titun, HapMap yio ni awọn anfani ati ewu ti a ko ro tẹlẹ, ti a ko si mura de, jade.


Ibusọ | Nipa Asepọ | Esi | Itẹjade | Tutorial |
Ti ẹ ba ni ibere tabi asọsi, ẹ le kan si help@hapmap.org